Rheelwon - His Excellency, Peter Ayodele Fayose (lyrics)
- Rheelwon Creativities®
- Aug 27, 2022
- 2 min read
Updated: Jul 18

INTRO:
I'm real!!
[Dr BT Gold on the mix]
Yeah yeah...
Yeah yeah ah!!
Ọmọ ju ọmọ lọ, ọba ju ọba lọ
Ọmọ ju ọmọ lọ, ọba ju ọba lọ
Àgbáyé 1...
Kàbìtì, sọ fún wọn
HOOK:
(Òṣòkòmọlẹ̀) Ìmọ́lẹ̀
Ẹyẹ bíi ọ̀kín ò sí o
(Òṣòkòmọlẹ̀)
Olúwa ló ń gbéniga oh, débi gíga oh
(Òṣòkòmọlẹ̀) Ìmọ́lẹ̀
Ẹyẹ bíi ọ̀kín ò sí ó o ò
(Òṣòkòmọlẹ̀)
Ṣẹti gbọ́, tẹbá ti rọ́ba oh, kẹya tẹríba oh
Òṣòkòmọlẹ̀) Ìmọ́lẹ̀
Ẹyẹ bíi ọ̀kín ò sí o
(Òṣòkòmọlẹ̀)
Olúwa ló ń gbéniga oh, débi gíga oh
(Òṣòkòmọlẹ̀) Ìmọ́lẹ̀
Ẹyẹ bíi ọ̀kín ò sí ó o ò
(Òṣòkòmọlẹ̀)
Ṣẹti gbọ́, tẹbá ti rọ́ba oh, kẹya tẹríba oh
PRE-CHORUS:
(Òṣòkò) One man for the people
(Òṣòkò) Strong man for the people
(Òṣòkò) Thumbs up for the hero
(Òṣòkò) 16-0!
(Òṣòkò) One man for the people
(Òṣòkò) Strong man for the people
(Òṣòkò) Thumbs up for the hero
(Òṣòkò) 16-0!!
CHORUS:
Our man, His Excellency
Peter Ayodele
Fayose, I just wanna say
Ride on, ride on, action icon
Our man, His Excellency
Peter Ayodele
Fayose, I just wanna say
Ride on, ride on, action icon
VERSE:
(Òṣòkò) Kìnìún yàtọ̀ sẹ́kùn
(Òṣòkò) Ọba ní kò sẹ́kún
(Òṣòkò) Wọ́n ní àlááfíà
Òhun la maa rí, la maa rí, kòní séwu
(Òṣòkò) Ṣèbí ká káyọ̀délé
(Òṣòkò) Olúwayóòṣé
(Òṣòkò) Ẹ lọ múra, kò séré
Wobi taa badé, málo kóyán wa kéré eh
(Òṣòkò) Ah! Kìràkìtà ò dọlà ah ah (Hey!)
Olúwa ní ṣolá ah ah (Hah!)
Kò sẹ́ni tó mọ̀la ah ah ah
Iṣẹ́ ta bá ṣáà ti ṣe ni kó lérè (Ẹn!)
Ta bá dẹ̀ ti ṣòwò, ká jèrè (Ẹn!)
Lọ́lá Olúwa, èmi á jèrè (eeeh...)
Baba ti fàṣẹ si
('ṣẹsi, Kàbìtì, sọ fún wọn)
HOOK:
Òṣòkòmọlẹ̀) Ìmọ́lẹ̀
Ẹyẹ bíi ọ̀kín ò sí o
(Òṣòkòmọlẹ̀)
Olúwa ló ń gbéniga oh, débi gíga oh
(Òṣòkòmọlẹ̀) Ìmọ́lẹ̀
Ẹyẹ bíi ọ̀kín ò sí ó o ò
(Òṣòkòmọlẹ̀)
Ṣẹti gbọ́, tẹbá ti rọ́ba oh, kẹya tẹríba oh
PRE-CHORUS:
(Òṣòkò) One man for the people
(Òṣòkò) Strong man for the people
(Òṣòkò) Thumbs up for the hero
(Òṣòkò) 16-0!
(Òṣòkò) One man for the people
(Òṣòkò) Strong man for the people
(Òṣòkò) Thumbs up for the hero
(Òṣòkò) Ah! 16-0!!
CHORUS:
Our man, His Excellency
Peter Ayodele
Fayose, I just wanna say
Ride on, ride on, action icon
Our man, His Excellency
Peter Ayodele
Fayose, I just wanna say
Ride on, ride on, action icon
OUTRO:
Málo kóbá mi
Lálá tó ròkè, wọ́n ní ilẹ̀
Òṣùpá tó ń tan ìmólè
Ṣólè jábọ́ ni? Láí láí!
Málo kóbá mi
Lálá tó ròkè, wọ́n ní ilẹ̀
Òṣùpá tó ń tan ìmólè ah
Ṣólè jábọ́ ni? Láí láí!
Do you like this song? You can listen to or download the song for free on this website's music page. Click here to proceed to the music page.
Thanks for reading!
Please share your opinions and let me know what you think in the comments section. If you have any questions, please ask. Don't forget to like and share. Thank you.
Comments